1 Sámúẹ́lì 2:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọmọ náà Sámúẹ́lì ń dàgbà, ó sì rí ojúrere lọ́dọ̀ Olúwa, àti ènìyàn pẹ̀lú.

1 Sámúẹ́lì 2

1 Sámúẹ́lì 2:17-29