1 Sámúẹ́lì 2:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Élì súre fún Elikánà àti aya rẹ̀ pé, “Kí Olúwa fún ọ ní irú-ọmọ láti ara obìnrin yìí wá, nítorí ẹ̀bùn tí ó béèrè tí ó sì tún fún Olúwa.” Wọ́n sì lọ sí ilé wọn.

1 Sámúẹ́lì 2

1 Sámúẹ́lì 2:16-22