1 Sámúẹ́lì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ó fọ àwọn ọ̀tá Olúwa túútúú;láti ọrun wá ni yóò sánààrá sí wọn; Olúwa yóò ṣe ìdájọ́ òpin ayé.“Yóò fi agbára fún ọba rẹ̀,yóò si gbé ìwo ẹni-àmì-òróró rẹ̀ sókè.”

1 Sámúẹ́lì 2

1 Sámúẹ́lì 2:1-16