1 Sámúẹ́lì 19:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Míkálì gbé ère ó sì tẹ́ e lórí ibùsùn, ó sì fi irun ewúrẹ́ sí ibi orí rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 19

1 Sámúẹ́lì 19:11-18