1 Sámúẹ́lì 18:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí wọ́n ṣe ń jó, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń kọrin pé:“Ṣọ́ọ̀lù pa ẹgbẹ̀rún tirẹ̀Dáfídì sì pa ẹgbẹgbàárún ní tirẹ̀.”

1 Sámúẹ́lì 18

1 Sámúẹ́lì 18:3-11