1 Sámúẹ́lì 18:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn olórí ogun Fílístínì tún tẹ̀ṣíwájú láti lọ sí ogun, ó sì ṣe lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n lọ, Dáfídì ṣe àṣeyọrí ju gbogbo àwọn ìránṣẹ́ Ṣọ́ọ̀lù lọ, orúkọ rẹ̀ sì gbilẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 18

1 Sámúẹ́lì 18:27-30