1 Sámúẹ́lì 17:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí òhun bá sì le jà tí ó sì pa mí, àwa yóò di ẹrú u yín, ṣùgbọ́n tí èmi bá lè ṣẹ́gun rẹ̀ tí mo sì pa á, ẹ̀yin yóò di ẹrú u wa, ẹ̀yin yóò sì máa sìn wá.”

1 Sámúẹ́lì 17

1 Sámúẹ́lì 17:8-15