1 Sámúẹ́lì 17:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì wọ ìhámọ́ra idẹ sí ẹsẹ̀ rẹ̀ àti àpáta idẹ kan láàrin ẹ̀yìn rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 17

1 Sámúẹ́lì 17:3-9