1 Sámúẹ́lì 17:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wo Dáfídì láti òkè délẹ̀, ó sì rí i wí pé ọmọ kékeré kùnrin ni, ó pọ́n ó sì lẹ́wà lójú, ó sì kẹ́gàn an rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 17

1 Sámúẹ́lì 17:38-50