1 Sámúẹ́lì 17:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì mú wàrà mẹ́wàá yìí lọ́wọ́ fún adarí ogun ti wọn. Wo bí àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ ṣe wà kí o sì padà wá fún mi ní àmìn ìdánilójú láti ọ̀dọ̀ wọn.

1 Sámúẹ́lì 17

1 Sámúẹ́lì 17:9-20