1 Sámúẹ́lì 17:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fílístínì kó àwọn ọmọ ogun rẹ̀ jọ fún ogun ní Síkọ̀ ti Júdà. Wọ́n pàgọ́ sí Efesidámímù, láàárin Síkọ̀ àti Ásékà,

1 Sámúẹ́lì 17

1 Sámúẹ́lì 17:1-9