1 Sámúẹ́lì 15:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì mú Ágágì ọba Ámálékì láàyè, ó sì fi idà rẹ̀ kọlu gbogbo àwọn ènìyàn rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 15

1 Sámúẹ́lì 15:5-14