1 Sámúẹ́lì 15:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ nísinsìn yìí, kí o sì kọlu Ámálékì, kí o sì pa gbogbo ohun tí ó bá jẹ́ ti wọn ní àparun. Má ṣe dá wọn sí, pa ọkùnrin àti obìnrin wọn, ọmọ kékeré àti ọmọ ọmú, màlúù àti àgùntàn, ìbákasẹ àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọn.”

1 Sámúẹ́lì 15

1 Sámúẹ́lì 15:1-6