1 Sámúẹ́lì 14:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Orúkọ ìyàwó rẹ̀ ní Áhínóámù ọmọbìnrin Áhímásì. Orúkọ olórí ogun rẹ̀ ni Ábínérì ọmọ Nérì arákùnrin baba Sọ́ọ̀lù.

1 Sámúẹ́lì 14

1 Sámúẹ́lì 14:40-52