1 Sámúẹ́lì 14:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣọ́ọ̀lù sì wí pé, “Ẹ dìbò láàárin èmi àti Jónátanì ọmọ mi.” Ìbò náà sì mú Jónátanì.

1 Sámúẹ́lì 14

1 Sámúẹ́lì 14:34-52