1 Sámúẹ́lì 14:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Olúwa tí ó gba Ísírẹ́lì là ti wà, bí ó bá ṣe pé a rí í lára Jónátanì ọmọ mi, ó ní láti kú.” Ṣùgbọ́n ẹnìkankan nínú wọn kò sọ ọ̀rọ̀ kan.

1 Sámúẹ́lì 14

1 Sámúẹ́lì 14:37-45