1 Sámúẹ́lì 14:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

lára wọn ni Áhíjà, tí ó wọ Éfódù. Òun ni ọmọ arákùnrin Íkábódù Áhítúbì, ọmọ Fínéhásì, ọmọ Élì, àlùfáà Olúwa ní Ṣílò kò sí ẹni tí ó mọ̀ pé Jónátanì ti lọ.

1 Sámúẹ́lì 14

1 Sámúẹ́lì 14:1-8