1 Sámúẹ́lì 13:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó sì ti ń parí rírú ẹbọ náà, Sámúẹ́lì sì dé, Ṣọ́ọ̀lù sì jáde láti lọ kí i.

1 Sámúẹ́lì 13

1 Sámúẹ́lì 13:8-14