1 Sámúẹ́lì 12:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n ẹ rí i dájú pé, ẹ bẹ̀rù Olúwa, kí ẹ sì sìn ín nínú òtítọ́ pẹ̀lú gbogbo ọkàn an yín; Ẹ kíyèsí ohun ńlá tí ó ti ṣe fún un yín.

1 Sámúẹ́lì 12

1 Sámúẹ́lì 12:23-25