1 Sámúẹ́lì 12:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sámúẹ́lì sì dá wọn lóhùn pé, “Ẹ má bẹ̀rù, ẹ ti ṣe gbogbo búburú yìí; ṣíbẹ̀ ẹ má ṣe yípadà kúrò lọ́dọ̀ Olúwa, ṣùgbọ́n ẹ fi gbogbo àyà yín sin Olúwa.

1 Sámúẹ́lì 12

1 Sámúẹ́lì 12:18-25