1 Sámúẹ́lì 12:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òní kì í ha á ṣe ọjọ́ ìkórè ọkà àlìkámà bí? Èmi yóò ké pe Olúwa kí ó rán àrá àti òjò. Ẹ̀yin yóò sì mọ irú ohun búburú tí ẹ ti ṣe níwájú Olúwa nígbà tí ẹ̀ ń béèrè fún ọba.”

1 Sámúẹ́lì 12

1 Sámúẹ́lì 12:13-25