1 Sámúẹ́lì 11:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n Ṣọ́ọ̀lù wí pé, “A kì yóò pa ẹnikẹ́ni lónìí, nítorí lónìí yìí ni Olúwa gba Ísírẹ́lì là.”

1 Sámúẹ́lì 11

1 Sámúẹ́lì 11:6-15