1 Sámúẹ́lì 11:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Náhásì ará Ámónì gòkè lọ, ó sì dó ti Jabesi-Gílíádì, gbogbo ọkùnrin Jábésì sì wí fún Néhásì pé, “Bá wa ṣe ìpinnú, àwa yóò sì máa sìn ọ́.”

1 Sámúẹ́lì 11

1 Sámúẹ́lì 11:1-2