1 Sámúẹ́lì 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sámúẹ́lì sì mú ìgò kékeré tí òróró wà nínú rẹ̀, ó sì dà á sí orí Ṣọ́ọ̀lù. Ó sì fi ẹnu kò ó ní ẹnu, wí pé, “Olúwa kò ha tí fi òróró yàn ọ ní olóri í lórí ohun ìní rẹ̀?

1 Sámúẹ́lì 10

1 Sámúẹ́lì 10:1-5