1 Sámúẹ́lì 1:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin náà Elikánà, àti gbogbo àwọn ará ilé rẹ̀, gòkè lọ láti rúbọ ọdún sí Olúwa, àti láti sán ẹ̀jẹ́ rẹ̀.

1 Sámúẹ́lì 1

1 Sámúẹ́lì 1:14-26