1 Sámúẹ́lì 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hánà dá a lóhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ kọ́, Olúwa mi,” “Èmi ni obìnrin oníròbìnújẹ́. Èmi kò mu ọtí wáìnì tàbí ọtí líle; Èmi ń tú ọkàn mi jáde sí Olúwa ni.

1 Sámúẹ́lì 1

1 Sámúẹ́lì 1:12-24