1 Pétérù 5:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìjọ tí ń bẹ ní Bábílónì, tí a yàn, pẹ̀lú kí yín, bẹ́ẹ̀ sì ni Máàkù ọmọ mi pẹ̀lú.

1 Pétérù 5

1 Pétérù 5:5-14