1 Pétérù 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ẹ ní ìfẹ́ tí ó gbóná láàrin ara yín: nítorí ìfẹ́ ni ń bo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ṣẹ̀ mọ́lẹ̀.

1 Pétérù 4

1 Pétérù 4:7-16