1 Pétérù 4:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà ẹ jẹ́ kí àwọn tí ń jìyà gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ Ọlọ́run máa ṣe rere, fi ọkàn wọn lè Ẹlẹ́dàá olóòtọ́ lọ́wọ́.

1 Pétérù 4

1 Pétérù 4:15-19