1 Pétérù 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí a bá gàn yín nítorí orúkọ Kírísítì, ẹni ìbùkún ni yín: nítorí Ẹ̀mí Ògo àti ti Ọlọ́run bà lé yín (ní ọ̀dọ̀ tí wọn, wọ́n ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ ní ibi, ṣùgbọ́n ní ọ̀dọ̀ ti yín a yìn ín lógo.)

1 Pétérù 4

1 Pétérù 4:11-17