1 Pétérù 3:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí báyìí ni àwọn obìnrin mímọ́ ìgbaànì pẹ̀lú, tí wọ́n gbẹ́kẹ̀lé Ọlọ́run, fi sẹ ara wọn lọ́sọ̀ọ́, wọn a máa tẹríba fún àwọn ọkọ tiwọn.

1 Pétérù 3

1 Pétérù 3:3-11