1 Pétérù 2:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí fún ẹ̀yin ti ẹ gbà á gbọ́, ó ṣe iyebíye; ṣùgbọ́n fún àwọn tí kò gbà á gbọ́,“Òkúta tí àwọn ọ̀mọ̀lé kọ̀ sílẹ̀,òun ni ó di pàtàkì ìgún-ilé,”

1 Pétérù 2

1 Pétérù 2:2-11