1 Pétérù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùfẹ́ ọ̀wọ́n, mo bẹ̀ yín, bí àlejò àti èrò, láti fà sẹ́hìn kúrò nínú ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara, tí ń ba ọkàn jagun;

1 Pétérù 2

1 Pétérù 2:4-14