1 Pétérù 1:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn wọ̀nyìí sì wáyé ìdánwò ìgbàgbọ́ yín tí ó ni iye lórí ju wúrà, ti ń ṣègbé lọ, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé iná ni a fi ń dán an wò, lè yọrísí ìyìn àti ògo àti ọlá ni ìgbà ìfarahàn Jésù Kírísítì.

1 Pétérù 1

1 Pétérù 1:2-16