1 Pétérù 1:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí a ti tún yín bí, kì í ṣe láti inú ìdíbàjẹ́ wá, bí kò ṣe èyí ti kì í díbàjẹ́ nípa ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tí ń bẹ láàyè tí ó sì dúró.

1 Pétérù 1

1 Pétérù 1:15-25