1 Pétérù 1:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àní ẹ̀yin tí o tipasẹ̀ rẹ̀ gba Ọlọ́run gbọ́, ẹni ti ó jí i dìde kúrò nínú òkú, tí ó sì fi ògo fún un; kí ìgbàgbọ́ àti ìrétí yín lè wà lọ́dọ̀ Ọlọ́run.

1 Pétérù 1

1 Pétérù 1:14-25