1 Pétérù 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níwọ̀nbí ẹ̀yin ti mọ̀ pé a kò fi ohun ìdíbàjẹ́ rà yín pàdà, bí fàdákà tàbí wúrà kúrò nínú ìwà asán yín, tí ẹ̀yin ti jogún láti ọ̀dọ̀ àwọn baba yín.

1 Pétérù 1

1 Pétérù 1:12-23