1 Pétérù 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n ń wádìí ìgbà wo tàbí irú sáà wo ni Ẹ̀mí Kírísítì tí ó wà nínú wọn ń tọ́ka sí, nígbà tí ó jẹ́rìí ìyà Kírísítì àti ògo tí yóò tẹ̀lé e.

1 Pétérù 1

1 Pétérù 1:9-15