1 Ọba 9:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hírámù sì rán àwọn ènìyàn rẹ̀, àwọn atukọ̀ tí ó mọ òkun, pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́ Sólómónì.

1 Ọba 9

1 Ọba 9:25-28