1 Ọba 9:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ìyẹn ni pé àwọn ọmọ wọn tí ó kù ní ilẹ̀ náà, tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kò le parun pátapáta, àwọn ni Sólómónì bu iṣẹ́ ìrú fún títí di òní yìí.

1 Ọba 9

1 Ọba 9:12-24