1 Ọba 9:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì ọba sì fi ogún ìlú ní Gálílì fún Hírámù ọba Tírè, nítorí tí Hírámù ti bá a wá igi kédárì àti igi fírì àti wúrà gẹ́gẹ́ bí gbogbo ìfẹ́ rẹ̀.

1 Ọba 9

1 Ọba 9:4-16