1 Ọba 9:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nígbà tí Solómónì sì parí kíkọ́ ilé Olúwa àti ààfin ọba, tí ó sì ti ṣe gbogbo nǹkan tí ó ń fẹ́ láti ṣe,

2. Olúwa sì farahàn án ní ìgbà kejì, bí ó ti farahàn án ní Gíbíónì.

1 Ọba 9