1 Ọba 8:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí tí àwọn ènìyàn yóò gbọ́ orúkọ ńlá rẹ, àti ọwọ́ agbára rẹ, àti nínà apá rẹ, nígbà tí ó bá sì wá, tí ó sì gbàdúrà sí ìhà ilé yìí,

1 Ọba 8

1 Ọba 8:41-48