1 Ọba 8:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O sì ti pa ìlérí rẹ mọ́ fún ìránṣẹ́ rẹ Dáfídì baba mi; pẹ̀lú ẹnu rẹ ni ìwọ ṣe ìlérí, o sì mú u ṣẹ pẹ̀lú ọwọ́ rẹ, bí ó ti rí lónìí.

1 Ọba 8

1 Ọba 8:23-28