1 Ọba 6:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ya àwòrán kérúbù, àti ti igi ọ̀pẹ àti ti ìtànná ewéko sí ara wọn, ó sì fi wúrà bò ó, èyí tí ó tẹ́ sórí ibi tí ó gbẹ́.

1 Ọba 6

1 Ọba 6:33-38