1 Ọba 6:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti lára ilẹ̀kùn igi ólífì náà ni ó ya àwòrán àwọn kérúbù, igi ọ̀pẹ àti ti ìtànná ewéko sí, ó sì fi wúrà bò wọ́n, ó sì tan wúrà sí ara àwọn kérúbù àti sí ara igi ọ̀pẹ.

1 Ọba 6

1 Ọba 6:27-38