1 Ọba 6:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Inú ilé náà sì jẹ́ Kédárì, wọ́n ṣe iṣẹ́ ọnà rẹ̀ pẹ̀lú ìtàkùn àti ìtànná. Gbogbo rẹ̀ sì jẹ́ Kédárì; a kò sì rí òkúta kan níbẹ̀.

1 Ọba 6

1 Ọba 6:9-23