1 Ọba 6:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó pín ogún ìgbọ̀nwọ́ sí ẹ̀yìn ilé náà, láti ilẹ̀ dé àjà ilé ni ó fi pákó kọ́, èyí ni ó kọ sínú, fún ibi tí a yà sí mímọ́ àní ibi mímọ́ jùlọ.

1 Ọba 6

1 Ọba 6:11-21