1 Ọba 4:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ní òye ju gbogbo ènìyàn lọ, ju Étanì, ará Ésírà, àti Hémánì àti Kálíkólì, àti Darà àwọn ọmọ Máhólì lọ. Òkìkí rẹ̀ sì kàn ní gbogbo orílẹ̀ èdè yíká.

1 Ọba 4

1 Ọba 4:24-33