1 Ọba 4:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Màlúù mẹ́wàá (10) tí ó sanra, àti ogún (20) màlúù láti inú pápá wá, àti ọgọ́rùn-ún (100) àgùntàn àti ewúrẹ́, láìka àgbọ̀nrín àti egbin, àti ogbúgbu, àti ẹyẹ tí ó sanra.

1 Ọba 4

1 Ọba 4:19-33